Orin Dafidi 106:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó fi wọ́n lé àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn lọ́wọ́,títí tí àwọn tí ó kórìíra wọn fi jọba lé wọn lórí.

Orin Dafidi 106

Orin Dafidi 106:35-45