Orin Dafidi 106:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n fi ìwà burúkú wọn mú OLUWA bínú,àjàkálẹ̀ àrùn sì bẹ́ sílẹ̀ láàrin wọn.

Orin Dafidi 106

Orin Dafidi 106:26-35