Orin Dafidi 106:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó gbà wọ́n là lọ́wọ́ àwọn tí ó kórìíra wọn,ó sì kó wọn yọ lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá wọn.

Orin Dafidi 106

Orin Dafidi 106:1-15