Orin Dafidi 105:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ máa fi orúkọ mímọ́ rẹ̀ yangàn,kí ọkàn àwọn tí ń wá OLUWA ó máa yọ̀.

Orin Dafidi 105

Orin Dafidi 105:1-6