Orin Dafidi 105:24 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA mú kí àwọn eniyan rẹ̀ pọ̀ sí i,ó sì mú kí wọ́n lágbára ju àwọn ọ̀tá wọn lọ.

Orin Dafidi 105

Orin Dafidi 105:21-28