Orin Dafidi 105:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní, “Ẹ kò gbọdọ̀ fọwọ́ kan ẹni àmìòróró mi,ẹ kò sì gbọdọ̀ ṣe àwọn wolii mi níbi.”

Orin Dafidi 105

Orin Dafidi 105:9-23