Orin Dafidi 104:6 BIBELI MIMỌ (BM)

O fi ibú omi bò ó bí aṣọ,omi sì borí àwọn òkè ńlá.

Orin Dafidi 104

Orin Dafidi 104:1-14