Orin Dafidi 104:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni tí ó wo ilẹ̀, tí ilẹ̀ mì tìtì,tí ó fọwọ́ kan òkè, tí wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí yọ èéfín.

Orin Dafidi 104

Orin Dafidi 104:25-35