Orin Dafidi 104:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Láti ibùgbé rẹ lókè ni o tí ń bomi rin àwọn òkè ńlá.Ilẹ̀ sì mu àmutẹ́rùn nípa iṣẹ́ ọwọ́ rẹ.

Orin Dafidi 104

Orin Dafidi 104:9-23