Orin Dafidi 103:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ yin OLUWA, gbogbo iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀,níbi gbogbo ninu ìjọba rẹ̀.Yin OLUWA, ìwọ ọkàn mi.

Orin Dafidi 103

Orin Dafidi 103:16-22