Orin Dafidi 103:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn títí ayé ni ìfẹ́ OLUWA tí kì í yẹ̀,sí àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ̀,òdodo rẹ̀ wà lára arọmọdọmọ wọn.

Orin Dafidi 103

Orin Dafidi 103:16-22