Orin Dafidi 103:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí baba ti máa ń ṣàánú àwọn ọmọ rẹ̀,bẹ́ẹ̀ ni OLUWA máa ń ṣàánú àwọntí ó bá bẹ̀rù rẹ̀.

Orin Dafidi 103

Orin Dafidi 103:5-22