Orin Dafidi 102:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn óo parẹ́ ṣugbọn ìwọ yóo wà títí lae;gbogbo wọn yóo gbó bí aṣọ,o óo pààrọ̀ wọn bí aṣọ;wọn yóo sì di ohun ìpatì.

Orin Dafidi 102

Orin Dafidi 102:19-28