Orin Dafidi 101:3 BIBELI MIMỌ (BM)

N kò ní gba nǹkan burúkú láyè níwájú mi.Mo kórìíra ìṣe àwọn tí wọ́n tàpá sí Ọlọrun.N kò sì ní bá wọn lọ́wọ́ sí nǹkankan.

Orin Dafidi 101

Orin Dafidi 101:1-7