Orin Dafidi 10:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó fara pamọ́ bíi kinniun tí ó wà ní ibùba;ó fara pamọ́ láti ki aláìní mọ́lẹ̀;ó mú aláìní, ó sì fi àwọ̀n fà á lọ.

Orin Dafidi 10

Orin Dafidi 10:5-18