Orin Dafidi 10:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹnu rẹ̀ kún fún èpè, ẹ̀tàn ati ìhàlẹ̀;ìjàngbọ̀n ati ọ̀rọ̀ ibi sì wà lábẹ́ ahọ́n rẹ̀.

Orin Dafidi 10

Orin Dafidi 10:1-15