Orin Dafidi 10:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣẹ́ eniyan burúkú ati aṣebi lápá,tú àṣírí gbogbo ìwà burúkú rẹ̀,má sì jẹ́ kí ọ̀kan ninu wọn farasin.

Orin Dafidi 10

Orin Dafidi 10:10-18