Orin Dafidi 1:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo dàbí igi tí a gbìn sí etí odòtí ń so ní àkókò tí ó yẹ,tí ewé rẹ̀ kì í rẹ̀.Gbogbo ohun tí ó bá dáwọ́lé níí máa yọrí sí rere.

Orin Dafidi 1

Orin Dafidi 1:1-6