Ọbadaya 1:17 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ṣugbọn ní òkè Sionini àwọn tí wọ́n bá sá àsálà yóo máa gbé,yóo sì jẹ́ òkè mímọ́;àwọn ọmọ Jakọbu yóo gba ohun ìní wọn pada.

Ọbadaya 1

Ọbadaya 1:14-20