Nọmba 9:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí OLUWA bá fún wọn láṣẹ ni wọ́n máa ń pàgọ́, nígbà tí ó bá sì tó fún wọn láṣẹ ni wọ́n tó máa ń gbéra.

Nọmba 9

Nọmba 9:18-23