Nọmba 9:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ìkùukùu náà tilẹ̀ dúró pẹ́ ní orí Àgọ́, àwọn ọmọ Israẹli ṣe ìgbọràn sí OLUWA, wọ́n dúró ninu àgọ́ wọn.

Nọmba 9

Nọmba 9:12-23