Nọmba 8:24 BIBELI MIMỌ (BM)

“Àwọn ọmọ Lefi yóo bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ìsìn wọn ninu Àgọ́ Àjọ láti ìgbà tí wọ́n bá ti di ẹni ọdún mẹẹdọgbọn.

Nọmba 8

Nọmba 8:18-26