Nọmba 8:2 BIBELI MIMỌ (BM)

kí ó sọ fún Aaroni pé, nígbà tí Aaroni bá tan fìtílà mejeeje, kí ó gbé wọn sórí ọ̀pá fìtílà kí wọ́n lè tan ìmọ́lẹ̀ siwaju ọ̀pá náà.

Nọmba 8

Nọmba 8:1-3