Nọmba 8:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí mo pa gbogbo àkọ́bí ní Ijipti ni mo ti ya gbogbo àkọ́bí ninu àwọn ọmọ Israẹli sọ́tọ̀ láti jẹ́ tèmi.

Nọmba 8

Nọmba 8:11-26