Nọmba 7:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn àwọn ọmọ Kohati ni Mose kò fún ní nǹkankan, nítorí pé àwọn ohun mímọ́ tí wọ́n máa ń fi èjìká rù ni iṣẹ́ ìsìn wọn jẹ mọ́.

Nọmba 7

Nọmba 7:6-12