Nọmba 7:83 BIBELI MIMỌ (BM)

Ahira, ọmọ Enani, kó akọ mààlúù meji ati àgbò marun-un, òbúkọ marun-un, ọ̀dọ́ àgbò marun-un, ọlọ́dún kọ̀ọ̀kan wá fún ẹbọ alaafia.

Nọmba 7

Nọmba 7:77-89