Nọmba 7:74 BIBELI MIMỌ (BM)

Ara àwọn ọrẹ rẹ̀ tún ni àwo kòtò kan tí wọ́n fi wúrà ṣe, tí ìwọ̀n rẹ̀ jẹ́ ṣekeli mẹ́wàá tí ó sì kún fún turari;

Nọmba 7

Nọmba 7:71-80