Nọmba 7:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Ara ọrẹ rẹ̀ tún ni: àwo kòtò kan tí wọ́n fi wúrà ṣe, tí ìwọ̀n rẹ̀ jẹ́ ṣekeli mẹ́wàá, tí ó sì kún fún turari,

Nọmba 7

Nọmba 7:35-40