Nọmba 6:21 BIBELI MIMỌ (BM)

“Èyí ni òfin Nasiri, ṣugbọn bí Nasiri kan bá ṣe ìlérí ju ẹbọ tí òfin là sílẹ̀ lọ, ó gbọdọ̀ mú ìlérí náà ṣẹ.”

Nọmba 6

Nọmba 6:13-26