Nọmba 4:9 BIBELI MIMỌ (BM)

“Wọn yóo fi aṣọ aláwọ̀ aró bo ọ̀pá fìtílà ati àwọn fìtílà rẹ̀ ati àwọn ohun tí à ń lò pẹlu rẹ̀ ati gbogbo ohun èlò òróró.

Nọmba 4

Nọmba 4:7-14