Nọmba 4:11 BIBELI MIMỌ (BM)

“Lẹ́yìn èyí, wọn óo da aṣọ aláwọ̀ aró bo pẹpẹ wúrà, wọn óo fi awọ ewúrẹ́ tí ń dán bò ó, wọn óo sì ti igi tí a fi ń gbé e bọ̀ ọ́.

Nọmba 4

Nọmba 4:6-12