Nọmba 36:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose bá pàṣẹ fún àwọn ọmọ Israẹli, gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti wí fún un, pé, “Ohun tí ẹ̀yà Manase sọ dára,

Nọmba 36

Nọmba 36:1-6