Nọmba 35:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ẹ má ṣe gba owó ìtanràn lọ́wọ́ ẹni tí ó jẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀ ìpànìyàn, pípa ni ẹ gbọdọ̀ pa òun náà.

Nọmba 35

Nọmba 35:25-34