Nọmba 33:44-47 BIBELI MIMỌ (BM)

44. Láti Obotu wọ́n lọ sí Òkè Abarimu ní agbègbè Moabu.

45. Láti Iyimu wọ́n lọ sí Diboni Gadi.

46. Láti Diboni Gadi wọ́n lọ sí Alimoni Dibilataimu.

47. Láti Alimoni Dibilataimu wọ́n lọ sí Òkè Abarimu níwájú Nebo.

Nọmba 33