Nọmba 33:17-21 BIBELI MIMỌ (BM)

17. Láti Kiburotu Hataafa wọ́n lọ sí Haserotu.

18. Láti Haserotu wọ́n lọ sí Ritima.

19. Láti Ritima wọ́n lọ sí Rimoni Peresi.

20. Láti Rimoni Peresi wọ́n lọ sí Libina.

21. Láti Libina wọ́n lọ sí Risa.

Nọmba 33