Nọmba 33:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ibi tí àwọn ọmọ Israẹli pàgọ́ sí ninu ìrìn àjò wọn láti ìgbà tí wọn ti kúrò ní Ijipti lábẹ́ àṣẹ Mose ati Aaroni nìwọ̀nyí:

Nọmba 33

Nọmba 33:1-9