Nọmba 32:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Jairi ọmọ Manase gbógun ti àwọn ìlú kan, ó sì gbà wọ́n. Ó sọ orúkọ wọn ní Hafoti Jairi.

Nọmba 32

Nọmba 32:37-42