Nọmba 31:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose sì rán wọn lọ sójú ogun lábẹ́ àṣẹ Finehasi ọmọ Eleasari alufaa, pẹlu àwọn ohun èlò mímọ́ ati fèrè fún ìdágìrì lọ́wọ́ rẹ̀.

Nọmba 31

Nọmba 31:5-11