Nọmba 31:48 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà ni àwọn olórí ogun àwọn olórí ẹgbẹẹgbẹrun ati ọgọọgọrun-un tọ Mose wá, wọ́n wí pé,

Nọmba 31

Nọmba 31:40-49