Nọmba 31:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìdajì rẹ̀ tí ó jẹ́ ti àwọn ọmọ ogun jẹ́ ẹgbaa mejidinlaadọsan-an ó lé ẹẹdẹgbẹjọ (337,500) aguntan.

Nọmba 31

Nọmba 31:30-40