Nọmba 31:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose bá sọ fún àwọn eniyan náà pé, “Ẹ múra ogun kí á lè gbógun ti àwọn ará Midiani, kí á sì fìyà jẹ wọ́n fún ohun tí wọ́n ṣe sí OLUWA.

Nọmba 31

Nọmba 31:2-7