Nọmba 3:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Surieli ọmọ Abihaili ni yóo jẹ́ olórí wọn. Kí wọ́n pàgọ́ tiwọn sí ìhà àríwá Àgọ́ Àjọ.

Nọmba 3

Nọmba 3:30-39