Nọmba 29:20 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ní ọjọ́ kẹta, ẹ óo máa fi ẹgbọ̀rọ̀ akọ mààlúù mọkanla, àgbò meji ati ọ̀dọ́ àgbò mẹrinla ọlọ́dún kan tí kò ní àbààwọ́n rúbọ.

Nọmba 29

Nọmba 29:15-21