Nọmba 28:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Èyí ni ẹbọ sísun ojoojumọ tí a ti fi ìlànà rẹ̀ lélẹ̀ ní òkè Sinai gẹ́gẹ́ bí ẹbọ sísun olóòórùn dídùn sí OLUWA.

Nọmba 28

Nọmba 28:1-7