Nọmba 28:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ẹ fi ọ̀dọ́ akọ mààlúù meji, ati àgbò kan, ati ọ̀dọ́ àgbò meje ọlọ́dún kọ̀ọ̀kan rú ẹbọ sísun olóòórùn dídùn sí OLUWA.

Nọmba 28

Nọmba 28:22-31