Nọmba 28:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Yàtọ̀ sí ẹbọ sísun ati ẹbọ ohun mímu ojoojumọ yìí, ẹ óo tún fi òbúkọ kan rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ sí OLUWA.

Nọmba 28

Nọmba 28:7-16