Nọmba 27:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Sì sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé nígbà tí ẹnìkan bá kú láìní ọmọkunrin, àwọn ọmọbinrin rẹ̀ yóo jogún ilẹ̀ ìní rẹ̀.

Nọmba 27

Nọmba 27:1-12