Nọmba 27:18 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA bá sọ fún Mose pé, “Mú Joṣua ọmọ Nuni, ẹni tí Ẹ̀mí èmi OLUWA wà ninu rẹ̀, gbé ọwọ́ rẹ lé e lórí,

Nọmba 27

Nọmba 27:11-22