Nọmba 26:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Selofehadi ọmọ Heferi kò bí ọmọkunrin kankan, àfi ọmọbinrin. Orúkọ àwọn ọmọbinrin Selofehadi ni Mahila, Noa, Hogila, Milika ati Tirisa.

Nọmba 26

Nọmba 26:23-37