Nọmba 26:15-18 BIBELI MIMỌ (BM)

15. Àwọn ọmọ Gadi ní ìdílé-ìdílé nìwọ̀nyí: ìdílé Sefoni, ìdílé Hagi, ati ìdílé Ṣuni;

16. ìdílé Osini, ati ìdílé Eri;

17. ìdílé Arodu ati ìdílé Areli.

18. Gbogbo àwọn tí a kà ninu ẹ̀yà Gadi jẹ́ ọ̀kẹ́ meji ó lé ẹẹdẹgbẹta (40,500).

Nọmba 26